Atọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Jump to navigation
Jump to search
No edit summary |
(Kò ní yàtọ̀)
|
Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 05:14, 1 Oṣù Èrèlé 2020
| Àdàkọ:Legend Àdàkọ:Legend Àdàkọ:Legend | Àdàkọ:Legend Àdàkọ:Legend |
Atọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn (AIE tabi HDI; Human Development Index) je statitiki àkópọ̀jáde tounje lilo lati toipo awon orile-ede bii ipele "idagbasoke eniyan" ati lati pinya awon orile-ede adagbasoke (idagbasoke giga), toundagbasoke (idagbasoke arin), ati aitodagbasoke (idagbasoke kekere). Statistiki na je kikopojade lati inu data lori igbe àdúródè, eko ati per-capita GIO tenikookan (gege bi olutoka iru igbesiaye) to je gbigbajo latowo awon orile-ede kookan to si je sise pelu formula yi:
- atọ́ka- =
nibi ti ati je iye kikerejulo ati gigajulo ti ayipada le ni, ni telentele.
Itokasi