Ìbádọ́gba àwọn coeficient: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ testwiki
Jump to navigation Jump to search
imported>T Cells
 
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 13:07, 23 Oṣù Agẹmọ 2016

Ní ìmọ̀ ìṣirò, ọ̀nà ìbádọ́gba àwọn coeficient tí a ń gbà yanjú ìṣiṣẹ́ ìbádọ́gba àwọn ìkọsílẹ̀ méjì bí polynomial fún àwọn ohun ìwúlò ti a kò mọ̀. Ó gbójú lé ìdálójú pé àwọn ìkọsílẹ̀ méjì jọrawọn bákannáan

Àpẹẹre ní ìdá gidi

Ká gbà wípé a fẹ́ lo partial fraction decomposition sí ìkọsílẹ̀  yìí:

1x(x1)(x2),

À ní, a fẹ́ gbe wá sí ipò yìí:

Ax+Bx1+Cx2,

Tí ó jẹ́ pé àwọn ìkọsílẹ̀ tí a kò mọ yí jẹ́ A, B àti C. Ìlọ́polọ́po formulas yìí pẹ̀lú x(x − 1)(x − 2) sọ méjèèjì di àwọn  polynomial méjì, tí ó bára dọ́gba:

A(x1)(x2)+Bx(x2)+Cx(x1)=1,