Àgbérò Pythagoras

Àgbérò Pythagoras ninu mathematics, je ibasepo ninu Jeometri Euklid larin awon egbe meteta anigunmeta onigunrege. O so pe:
Ninu anigunmeta rege ti iba je, itobi alopomeji ti egbe re je hypotenusi (egbe ti o ko ju si igun rege) dogba mo aropo awon itobi awon alopomeji ti won je ti egbe meji to ku (egbe mejeji ti won pinu si ibi ti igun rege wa).
A le ko agbero yi sile gege bi asedogba:
nibiti c ti duro fun gigun hypotenusi, ti a ati b si duro fun awon gigun awon egbe meji to ku.[1]
Agbero yii n jẹ orukọ pelu ọlọgbọn Giriisi Pythagoras, ti a bi ni akoko 570 BC. Ilana naa ti jẹ afihan ni ọpọlọpọ igba nipasẹ ọpọlọpọ awọn ọna oriṣiriṣi. Awọn oniruuru ẹri naa, pẹlu awọn ẹri jiometiri ati awọn ẹri algebra, ti wa fun ẹgbẹẹgbẹrun ọdun.