Nọ́mbà oníìpín

Lát'ọwọ́ testwiki
Àtúnyẹ̀wò ní 11:39, 11 Oṣù Ẹ̀rẹ̀nà 2013 l'átọwọ́ imported>Legobot
(ìyàtọ̀) ← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju | Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí (ìyàtọ̀) | Àtúnyẹ̀wò tótuntunju → (ìyàtọ̀)
Jump to navigation Jump to search
Idamerin

Àdàkọ:Nomba Ninu imo Mathematiki, nomba oniipin (rational number) ni nomba ti a le ko le gege be ipin nọ́mbà odidi meji. Nomba bi ab, to je pe b ki se odo.

A le ko awon nomba oniipin ni opolopo ona, fun apere 36=24=12, sugbon o d'ero julo nigbati a ati b ko ba ni nomba kanna ti a le fi pin won a fi 1.



Àdàkọ:Ekunrere