Atọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn
Jump to navigation
Jump to search
| Àdàkọ:Legend Àdàkọ:Legend Àdàkọ:Legend | Àdàkọ:Legend Àdàkọ:Legend |
Atọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn (AIE tabi HDI; Human Development Index) je statitiki àkópọ̀jáde tounje lilo lati toipo awon orile-ede bii ipele "idagbasoke eniyan" ati lati pinya awon orile-ede adagbasoke (idagbasoke giga), toundagbasoke (idagbasoke arin), ati aitodagbasoke (idagbasoke kekere). Statistiki na je kikopojade lati inu data lori igbe àdúródè, eko ati per-capita GIO tenikookan (gege bi olutoka iru igbesiaye) to je gbigbajo latowo awon orile-ede kookan to si je sise pelu formula yi:
- atọ́ka- =
nibi ti ati je iye kikerejulo ati gigajulo ti ayipada le ni, ni telentele.
Itokasi