Òbìrípo

Lát'ọwọ́ testwiki
Jump to navigation Jump to search
Òbìrípo

Ninu mathimatiki òbìrípo (Circle) pelu arin C ati ilatotan r, je irisi aniwonile to je akojopo awon ojuami ati ijinasi won si arin ti a n pe ni ilatotan (radius).

Iyipo je Ila-alajapo (curve)ti o ti; ti o si pin pepe si apa inu ati ode. Ibu re ni a mo si ayika (circumference). Inu re ni a n pe ni abọ́ (disk). Ọfà (arc) si ni apa iwapapo pato kan lori iyipo na.

Agbeyewo

Idogba fun iyipo

Ti a ba ni ona ipoidojuko x-y, iyipo to ni arin ni (a, b) ati ilatotan r je akojopo gbogbo ojuami (x, y) to fi je pe

(xa)2+(yb)2=r2

Ti o ba je pe ni ojuibere (0, 0) (origin) ni arin re wa, a le so afise dero bayi,


x2+y2=r2 

Be si ni tangenti yio je


xx1+yy1=r2 

nigbati x1, y1 si je ipoidojuko ojuami kanna won.


x=a+rcost,
y=b+rsint

(xy)

ax2+ay2+2b1xz+2b2yz+cz2=0


Àdàkọ:Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́

Itokasi

Àdàkọ:Reflist