Gbòngbò alágbáraméjì

Lát'ọwọ́ testwiki
Jump to navigation Jump to search

Ninu imo isiro gbòngbò alágbáraméjì tabi gbongbo ìlọ́poméjì (square root) fun nomba x je nomba r ti yio je r2=x tabi pe nomba r ti alagbarameji re (ti a ba so di pupo pelu ara re) je x.

Àdàkọ:Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́